الفاتحة
Al-Fatihah
Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀
Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniNí orúkọ Allāhu, Àjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run.[1]
- Abu Rahimah Mikael AykyuniGbogbo ẹyìn[1] ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa[2] gbogbo ẹ̀dá (àgbáńlá ayé àti ọ̀run),
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÀjọkẹ́-ayé, Àṣàkẹ́-ọ̀run,
- Abu Rahimah Mikael AykyuniỌba Olùkápá-ọjọ́-ẹ̀san.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÌwọ nìkan ni à ń jọ́sìn fún. Ọ̀dọ̀ Rẹ nìkan sì ni à ń wá ìrànlọ́wọ́ sí.[1]
- Abu Rahimah Mikael AykyuniFi ẹsẹ̀ wa rinlẹ̀ l’ójú ọ̀nà tààrà (ẹ̀sìn ’Islām),[1]
- Abu Rahimah Mikael Aykyuniọ̀nà àwọn tí O ṣe ìdẹ̀ra fún, yàtọ̀ sí (ọ̀nà) àwọn ẹni-ìbínú (ìyẹn, àwọn yẹhudi) àti (ọ̀nà) àwọn olùṣìnà (ìyẹn, àwọn nasọ̄rọ̄).