الماعون
Al-Ma'un
Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀
Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.
بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
- Abu Rahimah Mikael AykyuniSọ fún mi nípa ẹni tó ń pe Ọjọ́ Ẹ̀san ní irọ́!
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÌyẹn ni ẹni tó ń lé ọmọ-òrukàn dànù.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniKò sì níí gbìyànjú láti bọ́ mẹ̀kúnnù.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÈgbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;[1]
- Abu Rahimah Mikael Aykyuniàwọn tó ń gbàgbé láti kírun wọn ní àsìkò rẹ̀;
- Abu Rahimah Mikael Aykyuniàwọn tó ń ṣe ṣekárími;
- Abu Rahimah Mikael Aykyuniàti pé wọ́n ń hánnà ohun èlò (fún àwọn ènìyàn).