الكوثرAl-Kawthar Sūrah 108 · ti Mọkkah · āyah 3 · Ètò ìsọ̀kalẹ̀: 15 KíkọPẹ̀lú àmìLáìsí àmìEgungun Ìtúmọ̀ ọ̀rọ̀ Kíkà ní lẹ́tà Látìnì Àwọn ìtúmọ̀Abu Rahimah Mikael Aykyuni+ Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀. بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ108:1إِنَّآأَعْطَيْنَٰكَٱلْكَوْثَرَ١Abu Rahimah Mikael AykyuniDájúdájú Àwa fún ọ ní ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oore.108:2فَصَلِّلِرَبِّكَوَٱنْحَرْ٢Abu Rahimah Mikael AykyuniNítorí náà, kírun fún Olúwa rẹ, kí o sì gúnran (fún Un).108:3إِنَّشَانِئَكَهُوَٱلْأَبْتَرُ٣Abu Rahimah Mikael AykyuniDájúdájú, ẹni tó ń bínú rẹ, òun ni kò níí lẹ́yìn. Sūrah tó ṣáájúAl-Ma'unSūrah tó kànAl-Kafirun