الناس

An-Nas

Sūrah 114 · ti Mọkkah · āyah 6 · Ètò ìsọ̀kalẹ̀: 21

Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀

Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniSọ pé: “Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniỌba àwọn ènìyàn,
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniỌlọ́hun àwọn ènìyàn,[1]
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuniníbi aburú (aṣ-Ṣaetọ̄n) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu[1]).
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuni(aṣ-Ṣaetọ̄n ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuni(Ṣaetọ̄n náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn.”