الفلق

Al-Falaq

Sūrah 113 · ti Mọkkah · āyah 5 · Ètò ìsọ̀kalẹ̀: 20

Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀

Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniSọ pé: “Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuniníbi aburú ohun tí Ó dá,[1]
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuniàti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuniàti níbi aburú àwọn (òpìdán) tó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,
  1. Abu Rahimah Mikael Aykyuniàti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara.”