الكافرون
Al-Kafirun
Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀
Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.
بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
- Abu Rahimah Mikael AykyuniSọ pé: “Ẹ̀yin aláìgbàgbọ́,
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÈmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ̀ ń jọ́sìn fún.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniẸ̀yin náà kò jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniÈmi kò níí jọ́sìn fún ohun tí ẹ jọ́sìn fún sẹ́.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniẸ̀yin náà kò kú jọ́sìn fún Ẹni tí mò ń jọ́sìn fún.
- Abu Rahimah Mikael AykyuniTiyín ni ẹ̀sìn yín, tèmi sì ni ẹ̀sìn mi.”