المسد

Al-Masad

Sūrah 111 · ti Mọkkah · āyah 5 · Ètò ìsọ̀kalẹ̀: 6

Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀

Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniỌwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò.
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniÀwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà).
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniÓ sì máa wọ inú Iná eléjò fòfò.
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniÀti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná).
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniIgbà-ọ̀pẹ pọ̀npọ̀nràn máa wà ní ọrùn rẹ̀ (nínú Iná).