الإخلاص

Al-Ikhlas

Sūrah 112 · ti Mọkkah · āyah 4 · Ètò ìsọ̀kalẹ̀: 22

Kíkọ
Àwọn ìtúmọ̀

Tẹ ọ̀rọ̀ Lárúbáwá kan láti rí kíkà rẹ̀, ìgbékalẹ̀ rẹ̀ àti gbòǹgbò rẹ̀.

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniSọ pé: “Òun ni Allāhu, Ọ̀kan ṣoṣo.
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniAllāhu ni Aṣíwájú tí ẹ̀dá ní bùkátà sí níbi jíjọ́sìn fún Un àti títọrọ oore ní ọ̀dọ̀ Rẹ̀, tí Òun kò sì ní bùkátà sí wọn ní ọ̀nà kan kan.
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniKò bímọ. Wọn kò sì bí I.
  1. Abu Rahimah Mikael AykyuniKò sì sí ẹnì kan kan tí ó jọ Ọ́.”[1]